Lefitiku 26:30 BM

30 N óo wó àwọn ilé ìsìn yín gbogbo tí wọ́n wà lórí òkè, n óo wó àwọn pẹpẹ turari yín lulẹ̀; n óo kó òkú yín dà sórí àwọn oriṣa yín, ọkàn mi yóo sì kórìíra yín.

Ka pipe ipin Lefitiku 26

Wo Lefitiku 26:30 ni o tọ