Lefitiku 26:31 BM

31 N óo sọ àwọn ìlú yín di ahoro, àwọn ilé ìsìn yín yóo sì ṣófo, n kò ní gba ẹbọ yín mọ́.

Ka pipe ipin Lefitiku 26

Wo Lefitiku 26:31 ni o tọ