Lefitiku 7:25 BM

25 Nítorí pé a óo yọ ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ ọ̀rá ẹran tí a fi rú ẹbọ sísun sí OLUWA, kúrò lára àwọn eniyan Ọlọrun.

Ka pipe ipin Lefitiku 7

Wo Lefitiku 7:25 ni o tọ