Lefitiku 7:26 BM

26 Siwaju sí i, ẹ kò gbọdọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀ ní gbogbo ibùgbé yín, bí ó ti wù kí ó rí; ìbáà jẹ́ ti ẹyẹ tabi ti ẹranko.

Ka pipe ipin Lefitiku 7

Wo Lefitiku 7:26 ni o tọ