Lefitiku 8:17 BM

17 Ṣugbọn ó dáná sun ara ẹran akọ mààlúù náà, ati awọ rẹ̀, ati ìgbẹ́ rẹ̀ lẹ́yìn ibùdó náà, gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pàṣẹ fún un.

Ka pipe ipin Lefitiku 8

Wo Lefitiku 8:17 ni o tọ