Lefitiku 8:18 BM

18 Lẹ́yìn náà, Mose fa àgbò ẹbọ sísun kalẹ̀, Aaroni ati àwọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin sì gbé ọwọ́ wọn lé e lórí.

Ka pipe ipin Lefitiku 8

Wo Lefitiku 8:18 ni o tọ