Lefitiku 9:17 BM

17 Ó gbé ẹbọ ohun jíjẹ wá, ó bu ẹ̀kúnwọ́ kan ninu rẹ̀, ó sì sun ún lórí pẹpẹ ní ẹ̀gbẹ́ ẹbọ sísun ti òwúrọ̀.

Ka pipe ipin Lefitiku 9

Wo Lefitiku 9:17 ni o tọ