Lefitiku 9:18 BM

18 Ó pa akọ mààlúù ati àgbò ẹbọ alaafia fún àwọn eniyan, àwọn ọmọ rẹ̀ gbé ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ tọ̀ ọ́ wá, ó sì dà á sórí pẹpẹ náà yípo.

Ka pipe ipin Lefitiku 9

Wo Lefitiku 9:18 ni o tọ