Lefitiku 9:19 BM

19 Ó mú ọ̀rá akọ mààlúù, ati ti àgbò náà, pẹlu ìrù wọn tí ó lọ́ràá, ati ọ̀rá tí ó bo àwọn nǹkan inú wọn, ati kíndìnrín ati ẹ̀dọ̀ wọn.

Ka pipe ipin Lefitiku 9

Wo Lefitiku 9:19 ni o tọ