Nọmba 9:17 BM

17 Nígbà tí ìkùukùu yìí bá kúrò ní orí Àgọ́ Àjọ àwọn ọmọ Israẹli yóo tú àgọ́ wọn palẹ̀, wọn yóo sì lọ tún un pa níbi tí ìkùukùu náà bá ti dúró.

Ka pipe ipin Nọmba 9

Wo Nọmba 9:17 ni o tọ