Joṣ 19:50 YCE

50 Gẹgẹ bi aṣẹ OLUWA, nwọn fun u ni ilu ti o bère, ani Timnati-sera li òke Efraimu: o si kọ ilu na, o si ngbé inu rẹ̀.

Ka pipe ipin Joṣ 19

Wo Joṣ 19:50 ni o tọ