4 Nígbà kan, bí ó sì ti ń jẹun pẹ̀lú wọn, ó pàṣẹ yìí fún wọn: “Ẹ má ṣe kúrò ní Jerúsálémù, ṣùgbọ́n ẹ dúró de ẹ̀bùn tí Baba mi se ìlérí, èyí tí ẹ̀yin tí gbọ́ lẹ́nu mi.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:4 ni o tọ