Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:15 BMY

15 “Bí mo sì ti bẹ̀rẹ̀ sì sọ, Ẹ̀mi Mímọ́ sì bà lé wọn, gẹ́gẹ́ bí ó ti bà lé wa ni àtètèkọ́ṣe.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:15 ni o tọ