16 Nígbà náà ni mo rántí ọ̀rọ̀ Olúwa, bí ó ti wí pé, ‘Jòhánù fi omi bamitíìsì nítóòtọ́; ṣùgbọ́n a ó fi Ẹ̀mí Mímọ́ bamitíìsì yín.’
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:16 ni o tọ