Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:22 BMY

22 Ìròyìn nípa wọn sì dé etí ìjọ ti ó wà ni Jerúsálémù; wọ́n sì rán Bánábà lọ títí dé Áńtíókù;

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:22 ni o tọ