23 Nígbà ti ó dé ti ó sì rí ẹ̀rí oore-ọ̀fẹ́ Ọlọ́run, ó yọ̀, ó sì gba gbogbo wọn níyànjú pé, pẹ̀lú ìpinu ọkàn ni kí wọn fi ara mọ́ Olúwa.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 11:23 ni o tọ