2 Bí wọn sì ti ń jọ́sìn fún Olúwa, tí wọ́n sì ń gbààwẹ̀, Ẹ̀mí Mímọ́ wí pé, “Ẹ ya Bánábà àti Ṣọ́ọ̀lù sọ́tọ̀ fún mi fún iṣẹ́ ti mo ti pè wọ́n sí!”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:2 ni o tọ