Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:31 BMY

31 Ó sì farahàn lọ́jọ́ púpọ̀ fún àwọn tí ó bá a gòkè láti Gálílì wá sí Jerúsálémù, àwọn tí í ṣe ẹlẹ́rìí rẹ̀ nísinsìn yìí fún àwọn ènìyàn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 13:31 ni o tọ