11 Nígbà tí àwọn ènìyàn sì rí ohun tí Pọ́ọ̀lù ṣe, wọ́n gbé ohùn wọn sókè ni èdè Líkáóníà, wí pé, “Àwọn ọlọ́run sọ̀kalẹ̀ tọ̀ wá wá ni àwọ̀ ènìyàn!”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:11 ni o tọ