Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:15 BMY

15 “Ará, è é ṣe ti ẹ̀yin fi ń ṣe nǹkan wọ̀nyí? Ènìyàn bí ẹ̀yin náà ni àwa ń ṣe pẹ̀lú, ti a sì ń wàásù ìyìn rere fún yín, kí ẹ̀yin baà lè yípadà kúrò nínú ohun asán wọ̀nyí sí Ọlọ́run alààyè, tí ó dá ọ̀run àti ayé, àti òkun, àti ohun gbogbo tí ń bẹ nínú wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 14:15 ni o tọ