10 Nígbà tí ó sì tí rí ìran náà, lọ́gán ó múra láti lọ sí Makedóníà, a gbà á sí pé, Olúwa tí pè wá láti wàásù ìyìn rere fún wọn.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:10 ni o tọ