9 Ìran kan si hàn sì Pọ́ọ̀lù ni òru: Ọkùnrin kan ará Makedóníà dúró, ó sì ńbẹ̀ ẹ̀, wí pé, “Rékọjá wá ṣí Makedóníà, kí o sí ràn wá lọ́wọ́!”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 16:9 ni o tọ