16 Nígbà tí ọkùnrin tí ẹ̀mí búburú náà wà lára rẹ̀ sì fò mọ́ wọn, ó pá kúúrù mọ́ wọn, ó sì borí wọn, bẹ́ẹ̀ ni wọ́n sá jáde kúrò ní ilé náà ní ìhòòhò pẹ̀lú ni ìfarapa.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:16 ni o tọ