17 Ìròyìn yìí sì di mímọ̀ fún gbogbo àwọn Júù àti àwọn ará Gíríkì pẹ̀lú tí ó ṣe àtìpó ní Éfésù; ẹ̀rù sì ba gbogbo wọn, a sì gbé orúkọ Jésù Olúwa ga.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:17 ni o tọ