Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:32 BMY

32 Ǹjẹ́ àwọn kan ń wí ohun kan, àwọn mìíràn ń wí òmíran: nítorí àjọ di rúdurùdu; ọ̀pọ̀ ènìyàn ni kò sì mọ̀ ìdí ohun tí wọ́n tilẹ̀ fi péjọ pọ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:32 ni o tọ