33 Àwọn kan nínú àwujọ ń gún Alekisáńdérù, tí àwọn Júù tì síwájú, ní kẹ́ṣẹ́ láti ṣọ̀rọ̀ Alekisáńdérù sì juwọ́ sì wọn, òun ìbá sì wí ti ẹnu rẹ̀ fún àwọn ènìyàn.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:33 ni o tọ