Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:34 BMY

34 Ṣùgbọ́n nígbà tí wọ́n mọ̀ pé Júù ni, gbogbo wọn, ni ohùn kan, bẹ̀rẹ̀ ṣí kígbe fún bi wákàtí méjì pé, “Òrìṣà ńlá ni Dáyánà tí ará Éfésù!”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:34 ni o tọ