6 Nígbà tí Pọ́ọ̀lù sì gbé ọwọ́ lé wọn, Ẹ̀mí Mímọ́ sì bà lé wọn: wọ́n sì ń fọ́ èdè mìíràn, wọ́n sì ń sọ àsọtẹ́lẹ̀.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 19:6 ni o tọ