37 Gbogbo wọn sì sọkún gidigidi, wọ́n sì rọ̀ mọ́ Pọ́ọ̀lù lọ́rùn, wọ́n sì fi ẹnu kò ó lẹ́nu.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:37 ni o tọ