38 Inú wọn sì bàjẹ́ jùlọ fún ọ̀rọ̀ tí ó sọ pé, wọn kì yóò rí ojú òun mọ́, wọ́n sì sìn ín títí dé inú ọkọ̀.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 20:38 ni o tọ