1 Lẹ́yìn tí àwa ti kúrò lọ́dọ̀ wọn, tí a sì ṣíkọ̀, àwa bá ọ̀nà wa lọ tàrà sí Kúúsì. Ní ijọ́ kéjì a sì lọ sí Ródésì, àti gba ibẹ̀ lọ sí Pátarà:
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 21:1 ni o tọ