Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:18 BMY

18 mo sì rí Olúwa, ó ń sọ̀rọ̀ fún mi pé, ‘Kíá! Jáde kúrò ní Jerúsálémù kán-kán, nítorí wọn kì yóò gba ẹ̀rí rẹ nípa mi gbọ́.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:18 ni o tọ