19 “Èmi sì wí pé, ‘Olúwa, àwọn ènìyàn wọ̀nyí pàápàá mọ̀ pé èmi ti lọ láti inú sínágọ́gù kan sí èkejì láti máa sọ wọ́n sínú túbú àti láti máa lu àwọn tí ó gbà ọ́ gbọ́.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:19 ni o tọ