20 Nígbà tí a sì ta ẹ̀jẹ̀ Sítéfánù ẹlẹ́ríì rẹ sílẹ̀, èmi náà pẹ̀lú dúró níbẹ̀, mo sì ní ohùn sí ikú rẹ̀, mo sì ń se ìtọ́jú aṣọ àwọn ẹni tí ó pa á.’
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:20 ni o tọ