Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:28 BMY

28 Olórí-Ogun sì dáhùn wí pé, “Owó púpọ̀ ni mo fi ra ọlá ìbílẹ̀ yìí.”Pọ́ọ̀lù wí pé, “Ṣùgbọn a bí mi sínú rẹ̀ ni.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:28 ni o tọ