Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:29 BMY

29 Nítorí náà àwọn tí ó múra láti fi ọ̀rọ̀ wa lẹ́nu wò fà sẹ́yìn kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀: lójúkan náà. Ọlórí-ogun pẹ̀lú sì bẹ̀rù nígbà tí ó mọ̀ pé ọmọ ìbílẹ̀ Róòmù ní Pọ́ọ̀lù i ṣe, àti nítorí ó tí dè é.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 22:29 ni o tọ