Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:20 BMY

20 Ó sì wí pé, “Àwọn Júù fi ìmọ̀ sọ̀kan láti wá bẹ̀ ọ́, kí o mú Pọ́ọ̀lù sọ̀kalẹ̀ wá sí àjọ ìgbimọ̀ ní ọ̀la, bí ẹni pé àwọn ń fẹ́ bèèrè nǹkan dájúdájú nípa rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 23:20 ni o tọ