Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:22 BMY

22 Àgírípà sí wí fún Fésítúsì pé, “Èmi pẹ̀lú fẹ́ láti gbọ ọ̀rọ̀ ọkùnrin náà tìkááramì,” Ó sì wí pé, “Ní ọ̀la ìwọ ó gbọ́ ọ.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:22 ni o tọ