Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:23 BMY

23 Ní ọjọ́ kejì, tí Àgírípà àti Báníkè wọ ilé ẹjọ́ ti àwọn ti ẹ̀sọ́ púpọ̀ pẹ̀lú àwọn olórí ogun àti àwọn ènìyàn ńlá ní ìlú, Fẹ́sítúsì pàṣẹ, wọ́n sì mú Pọ́ọ̀lù jáde.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 25:23 ni o tọ