2 Kì í ṣe oore díẹ̀ ni àwọn alàìgbédè náà ṣe fún wa: nítorí ti wọ́n dáná, wọ́n sì gbà gbogbo wa sí ọ̀dọ̀ nítorí òjò ń rọ nígbà náà, àti nítorí òtútù.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 28:2 ni o tọ