Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:13 BMY

13 Nígbà tí wọ́n sì kíyèsí ìgboyà Pétérù àti Jòhánù, tí wọ́n mọ̀ pé, aláìkẹ́kọ̀ọ́ àti òpè ènìyàn ni wọn, ẹnu yà wọ́n, wọ́n sì wòye pé, wọ́n ti ń bá Jésù gbé.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:13 ni o tọ