Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:12 BMY

12 Kò sì sí ìgbàlà lọ́dọ̀ ẹlomìíràn; nítorí kò sí orúkọ mìíràn lábẹ́ ọ̀run ti a fifún ni nínú ènìyàn, nípa èyí tí a lè fi gbà wá là.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 4:12 ni o tọ