Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:14 BMY

14 Nítorí àwa gbọ́ o wí pé Jésù ti Násárẹ́tì yìí yóò fọ́ ibí yìí, yóò sì yí àṣà ti Mósè fifún wa padà.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:14 ni o tọ