15 Gbogbo àwọn tí ó sì jókò ni àjọ ìgbìmọ̀ tẹjúmọ́ Sítéfánù, wọ́n sì rí ojú rẹ̀ dàbí ojú ańgẹ́lì.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6
Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 6:15 ni o tọ