Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:44 BMY

44 “Àwọn baba wa ní àgọ́ ẹ̀rí pẹ̀lú wọn ní ijú. Èyí tí a se gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́run tí ó ba Mósè sọ̀rọ̀ pé kí ó ṣe é, gẹ́gẹ́ bí àpẹrẹ tí ó ti rí.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:44 ni o tọ