Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:45 BMY

45 Ti àwọn baba wa tí ó tẹ̀lé wọn sí mú bá Jóṣúà wá sí ilẹ̀-ìní àwọn aláìkọlà, tí Ọlọ́run lè jáde kúrò níwájú àwọn baba wa, títí dí àkókó Dáfídì.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 7:45 ni o tọ