Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:27 BMY

27 Ṣùgbọ́n Bánábà mú un, ó sì sìn ín lọ sọ́dọ̀ àwọn àpósítélì, ó sì sọ fún wọn bí ó ti rí Olúwa ní ọ̀nà, àti bí ó ti fi ìgboyà wàásù ní Dámásíkù ní orúkọ Jésù.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 9:27 ni o tọ