Diutaronomi 13:7 BM

7 oriṣa yìí kì báà jẹ́ èyí tí ó wà nítòsí, tí àwọn ará agbègbè yín ń bọ, tabi èyí tí ó jìnnà réré, tí àwọn tí wọ́n wà ní ilẹ̀ òkèèrè ń bọ.

Ka pipe ipin Diutaronomi 13

Wo Diutaronomi 13:7 ni o tọ