Diutaronomi 27:26 BM

26 “ ‘Ẹni ìfibú ni ẹnikẹ́ni tí kò bá pa gbogbo àwọn òfin yìí mọ́, kí ó sì máa tẹ̀lé wọn.’“Gbogbo eniyan yóo sì dáhùn pé, ‘Amin.’

Ka pipe ipin Diutaronomi 27

Wo Diutaronomi 27:26 ni o tọ