Diutaronomi 27:6 BM

6 Òkúta tí wọn kò gbẹ́ ni kí ẹ fi kọ́ pẹpẹ kan fún OLUWA Ọlọrun yín kí ẹ sì rú ẹbọ sísun sí i lórí rẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 27

Wo Diutaronomi 27:6 ni o tọ